RMQK Wisdom, mò kí ọga wá èmi àgbà àti olùkọ́ mí kewuyemi kewunla oga mí mò kí gbó gbó èmi lapapo mimọ mimọ ní fún àwọn Ẹ̀mí Ọlọ́run. Mó dúpé fún Ọlọ́run àti àwọn Ẹ̀mí pé mò jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn tó bá ẹ̀kọ́ àwọn bàbá wá yí pàdé. Thank you prof.
Adio Rafiou
سبوح قدوس رب الملائكة والروح
Mimọ mimọ mimọ mimọ ní fún àwon èmí ọlọhun
Mon prof vous résider pour toujours dans la paix et la joie Amen
Abduljelili Abdulrasheed
THE ONLY RMQK WISDOM MÍMNỌ́ MÍMNỌ́ MÍMNỌ́ Ọ̀PỌ̀LỌPỌ̀ ADUPE
Yussuf Ganiu Morenikeji
Thank you Proff Kewunla, Gbogbo igba ni emi n dupe fun Olorun, ati awon Baba RMQK. Emi agba ni Imole ti awon Emi mimo tan si gbobo agbaye. Imole yii koni wo lookun titi Aye raye, Emi agba ni omi AANU, IFOKANBALE, ITUSILE, ADEYORI ATI BEBE LOO. Awon ni GIFT ti awon RMQK fi tawa lore, Emi yi o ma gbe Emi ti igbeka, aponle ati ope to si ga. Kabiyesi Oluwa Mi. Emi mi n dupe, yi o si ma dupe titi aye raye. Igba ti mo bere Eko yii ni mo see mo bi Olorun se tobi to.
KABIYESI sir, eku agbale waa oooo.
Awon Baba RMQK yio ma se alekun, OGBON, IMO, OYE, ALAFIA ATI ANU ASE.
Elesho Haruna
RMQK WISDOM!!!
Taoreed Sunmola
Kabiesi, thanks for your precious lecture. Mimo, Mimo Mimo Mimo fun awon emi.
Olujimi Ojo
Baba ke pe fun wa o. Amin
Mojisola ademo
That is the truth
May you last for us.
Ademola Steven Omoriege
E seun sir.
Issac Tinuoye-John
Each lectures are filled with knowledge that maybe contrary to the norm we are familiar with but having a refreshing and profound view that demystify myths and corroborate our desire in oneness to live in love and unity. Confirming supremacy through the knowledge of the spirit is assuring and joyful.
Comments
10 responses to “RMQK ORIGIN 1”